Róòmù 2:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ tí o wí pé, kí ènìyàn má ṣe panṣágà, ìwọ ń ṣe panṣágà bí? Ìwọ tí o kóríra òrìṣà, ìwọ ń ja tẹ́ḿpìlì ní olè bí?

Róòmù 2

Róòmù 2:12-27