Róòmù 16:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gáíúsì, ẹni tí èmi àti gbogbo ìjọ gbádùn ìtọ́jú wa tí ó se náà fi ìkíni ránsẹ́.Érásítù, ẹni tí ó jẹ́ alábojútó isẹ́ ìlú, àti arákùnrin wa Kúárítù fi ìkíni wọn ránsẹ́.

Róòmù 16

Róòmù 16:14-25