Róòmù 16:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmí rọ̀ yín, ara, kí ẹ máa sọ àwọn tí ń fa ìyapa, àti àwọn tí ń mú ohun ìkọ̀sẹ̀ wá sí ọ̀nà yín, èyí tí ó lòdì sí ẹ̀kọ́ tí ẹ̀yin kọ́. Ẹ yà kúrò ní ọ̀dọ̀ wọn.

Róòmù 16

Róòmù 16:13-25