Róòmù 14:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìgbàgbọ́ ẹnìkọ̀ọ̀kan fi ààyè gbà á láti jẹ ohun gbogbo: sùgbọ́n ẹlòmíràn tí ó sì jẹ́ aláìlera ní ìgbàgbọ́ ń jẹ ewébẹ̀ nìkan.

Róòmù 14

Róòmù 14:1-5