Róòmù 13:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti èyí, bí ẹ ti mọ àkókò pé, ó ti tó wákàtí nísinsìnyí fún yín láti jí lójú orun: nítorí nísinsìn yìí ni ìgbàlà wa súnmọ́ etílé ju ìgbà tí àwa ti gbàgbọ́ lọ.

Róòmù 13

Róòmù 13:10-14