Róòmù 12:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tàbí ẹni tí ó ń gbani níyànjú, sí ìgbìyànjú; ẹni tí ń fi fún ni kí ó máa fi inú kan ṣe é; ẹni tí ń ṣe olórí, kí ó máa ṣe é ní ojú méjèèjì; ẹni tí ń sàánú, kí ó máa fi inú dídùn ṣe é.

Róòmù 12

Róòmù 12:3-14