Róòmù 12:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olùfẹ́, ẹ má ṣe gbẹ̀san ara yín, ṣùgbọ́n ẹ fi ààyè sílẹ̀ fún ìbínú; nítorí a ti kọ ọ́ pé, Olúwa wí pé, “Èmi ni ẹ̀san, èmi ó gbẹ̀san.”

Róòmù 12

Róòmù 12:11-21