Róòmù 11:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ti ìyìn rere, ọ̀ta ni wọ́n nítorí yín; bí ó sì ṣe ti ìyànfẹ́ ni, olùfẹ́ ni wọ́n nítorí ti àwọn baba.

Róòmù 11

Róòmù 11:23-31