Róòmù 11:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ará, èmi kò sá fẹ́ kí ẹ̀yin kí ó wà ní òpè ní ti ohun ìjìnlẹ̀ yìí, kí ẹ̀yin má baá ṣe ọlọgbọ́n ní ojú ara yín, pé ìfọ́jú bá Ísírẹ̀lì ní apákan, títí kíkún àwọn aláìkọlà yóò fi dé.

Róòmù 11

Róòmù 11:19-31