Róòmù 11:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìdí tí mo fi ń ṣe èyí ni láti mú kí wọn jowú nǹkan tí ẹ̀yin aláìkọlà ní, bóyá ní ọ̀nà yìí Ọlọ́run lè lò mí láti gba díẹ̀ là nínú wọn.

Róòmù 11

Róòmù 11:13-18