Róòmù 1:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Asọ̀rọ̀-ẹni-lẹ́yìn, akóríra Ọlọ́run, aláfojúdi, agbéraga, ahalẹ̀, aláròṣe ohun búburú, aṣàìgbọ́ràn sí òbí,

Róòmù 1

Róòmù 1:25-31