Róòmù 1:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n yí òtítọ́ Ọlọ́run sí èké, wọ́n sì ń forí balẹ̀ láti máa sin ẹ̀dá dípò ẹlẹ́dàá—ẹni tí ìyìn tọ́ sí láéláé. Àmín.

Róòmù 1

Róòmù 1:17-30