Róòmù 1:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

wọ́n sì yí ògo Ọlọ́run tí kìí díbàjẹ́ sí àwọn àwòrán ère bí i ti ènìyàn tí í díbàjẹ́ àti ti ẹyẹ, àti ti ẹranko ẹlẹ́sẹ̀ mẹ́rin àti ti ẹranko afàyàfà.

Róòmù 1

Róòmù 1:18-32