Òwe 9:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òmùgọ̀ obìnrin jẹ́ aláriwo;ó jẹ́ aláìlẹ́kọ̀ọ́ àti aláì ní ìmọ̀.

Òwe 9

Òwe 9:4-18