Òwe 8:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tẹ́tí, nítorí mo ní àwọn ohun iyebíye láti sọ;Mo ya ẹnu mi láti sọ àwọn ohun tí ó tọ̀nà,

Òwe 8

Òwe 8:1-15