Òwe 7:24-27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

24. Nítorí náà báyìí ẹ̀yin ọmọ mi, tẹ́tí sí mifọkàn sí nǹkan tí mo sọ.

25. Má ṣe jẹ́ kí ọkàn rẹ kí ó yà sí ọ̀nà rẹ̀,tàbí kí ó rìn lọ sí ipa ọ̀nà rẹ̀.

26. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni àwọn tí ó ti fà lulẹ̀Ogunlọ́gọ̀ àwọn alágbára ni ó ti pa.

27. Ilé e rẹ̀ ni ọ̀nà tààra sí iṣà òkú,tí ó lọ tààra sí àgbàlá ikú.

Òwe 7