Òwe 7:20-23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

20. Ó mú owó púpọ̀ lọ́wọ́kò sì ní darí dé kí ó tó di ọ̀sán.”

21. Pẹ̀lú ọ̀rọ̀ dídùn ó sì í lọ́nà;ó tàn án jẹ pẹ̀lú ẹnu dídùn.

22. Kíákíá ni ó tẹ̀lé ebí i màlúù tí ń lọ sí odò ẹranbí àgbọ̀nrín tí ó fẹ́ kẹsẹ̀ bọ pàkúté

23. títí tí ọ̀kọ̀ fi gún un ní ẹ̀dọ̀,bí ẹyẹ ṣe ń fẹ́ wọ inú okùn,Láì mọ̀ pé yóò gba ẹ̀mí òun.

Òwe 7