Òwe 6:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gba ara rẹ sílẹ̀, bí abo àgbọ̀nrín kúrò lọ́wọ́ ọdẹ,bí ẹyẹ kúrò nínú okùn àwọn pẹyẹpẹyẹ.

Òwe 6

Òwe 6:1-7