Òwe 6:34-35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

34. nítorí owú yóò ru ìbínú ọkọ sókè,kì yóò sì ṣàánú nígbà tí ó bá ń gbẹ̀san.

35. Kò ní gba nǹkankan bí ohun ìtanràn;yóò kọ àbẹ̀tẹ́lẹ̀, bí ó ti wù kí ó pọ̀ tó.

Òwe 6