Òwe 6:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ síi nínú ọkàn rẹ nítorí ẹwà rẹtàbí kí o jẹ́ kí ó fi ojú rẹ̀ fà ọ́ mọ́ra,

Òwe 6

Òwe 6:23-30