Òwe 5:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ṣùgbọ́n ní ìgbẹ̀yìngbẹ́yín, ó korò ju òróòro lọó mú bí idà olójú méjì.

Òwe 5

Òwe 5:1-5