Òwe 5:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Abo àgbọ̀nrín tó dára, ìgalà tí ó wu ni jọjọJẹ́ kí ọmú rẹ̀ tẹ́ ọ lọ́rùn nígbà gbogbojẹ́ kí ìfẹ́ rẹ̀ máa fà ọ́ títí láéláé

Òwe 5

Òwe 5:11-21