Òwe 4:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ mi, tẹ́tí sí ohun tí mo sọ;fetísílẹ̀ dáradára sí ọ̀rọ̀ mi

Òwe 4

Òwe 4:15-21