Òwe 31:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ojú dáradára a máa tan ni, ẹwà sì jẹ́ asánnítorí obìnrin tí ó bẹ̀rù Olúwa yẹ kí ó gba oríyìn

Òwe 31

Òwe 31:26-31