Òwe 30:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ipa idì ní òfuurufúipa ejò lórí àpátaipa ọkọ̀ ojú omi lójú agbami òkunàti ipa ọ̀nà ọkùnrin tí ó mú wúndíá lọ́wọ́.

Òwe 30

Òwe 30:10-29