Òwe 30:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ojú tí ń fi baba ṣẹ̀fẹ̀,tí ó kẹ́gàn ìgbọràn sí ìyáẹyẹ àkálá ẹ̀bá odò ni yóò yọ ọ́,igún yóò mú un jẹ.

Òwe 30

Òwe 30:10-27