Òwe 30:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ẹni tí ojú wọn gbéga nígbà gbogbo,tí ìwolẹ̀ wọn sì kún fún ìgbéraga.

Òwe 30

Òwe 30:12-21