Òwe 3:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ mi pa ìdájọ́ tí ó yè kooro mọ́ àti ìmọ̀yàtọ̀,má jẹ́ kí wọn lọ kúrò ní ibi tí ojú rẹ ti le tó wọn

Òwe 3

Òwe 3:16-25