Òwe 3:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Igi ìyè ni ó jẹ́ fún gbogbo ẹni tí ó bá gbàá;àwọn tí ó bá sì dìí mú yóò rí ìbùkún gbà.

Òwe 3

Òwe 3:17-24