Òwe 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ mi, má ṣe gbàgbé ẹ̀kọ́ mi.Ṣùgbọ́n pa òfin mi mọ́ sí ọkàn rẹ.

Òwe 3

Òwe 3:1-8