Òwe 29:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olódodo ń ṣaápọn nípa ìdájọ́ òtítọ́ fún àwọn tálákà,ṣùgbọ́n kò sí ohun tí ó kan ènìyàn búburú nínú irú rẹ̀.

Òwe 29

Òwe 29:3-9