Òwe 29:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Oníbìínú ènìyàn a ru ìjà sókè,Onínú-fùfù ènìyàn a sì máa dá ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀ṣẹ̀.

Òwe 29

Òwe 29:20-25