Òwe 28:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn tí ó kọ òfin sílẹ̀ a máa gbóríyìn fún ènìyàn búburúṣùgbọ́n àwọn tí ó pa òfin mọ́ kọjú ìjà sí ènìyàn búburú.

Òwe 28

Òwe 28:2-12