Òwe 28:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹni tí ó bá ènìyàn kan wí yóò rí ojú rere síi nígbẹ̀yìnju ẹni tí ó ní ètè ẹ̀tàn lọ.

Òwe 28

Òwe 28:19-28