Òwe 28:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba tí ó jẹ gàba lórí ìlú láì gbàmọ̀ràn kò gbọ́nṣùgbọ́n ẹni tí ó kórìíra èrè ìjẹkújẹ yóò gbádùn ọjọ́ gígùn.

Òwe 28

Òwe 28:7-26