Òwe 27:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò tẹ́ ikú àti ìparun lọ́rùn ríbẹ́ẹ̀ pẹ̀lú ni ojú ènìyàn kò rí ìtẹ́lọ́rùn rí.

Òwe 27

Òwe 27:18-24