Òwe 26:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lagbà fún ẹṣin, ìjánu fún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́àti pàṣán fún ẹ̀yìn aṣiwèrè.

Òwe 26

Òwe 26:1-9