Òwe 25:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí afẹ́fẹ́ gúṣù ti í mú òjò wá,bí ahọ́n tí ń sọ̀rọ̀ ẹ̀yìn ṣe ń mú ojú ìbínú wá.

Òwe 25

Òwe 25:19-27