Òwe 23:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni ó ni òsì? Ta ni ó ni ìbànújẹ́?Ta ni ó ni ìjà? Ta ni ó ni aṣọ̀? Ta ni ó ni ọgbẹ́ láìnídìí?

Òwe 23

Òwe 23:27-35