Òwe 23:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe fa ọwọ́ ìbáwí sẹ́yìn kúrò lára ọmọdé,nítorí pé bí ìwọ bá fi pàṣán nà án, òun kì yóò kú.

Òwe 23

Òwe 23:7-19