Òwe 22:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó lè mú ọ mọ dídájú ọ̀rọ̀ òtítọ́;kí ìwọ le máa fi ìdáhùn òtítọ́ fún àwọn tí ó rán ọ?

Òwe 22

Òwe 22:19-29