Òwe 22:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lé ẹlẹ́gàn sí ìta, ìjà yóò sì jáde;nítòótọ́ ìjà àti ẹ̀gàn yóò dẹ́kun.

Òwe 22

Òwe 22:9-20