Òwe 20:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Iyì ni ó jẹ́ fún ènìyàn láti sá fún ìjàṣùgbọ́n gbogbo aláìgbọ́n a máa tètè wá ìjà.

Òwe 20

Òwe 20:1-7