Òwe 20:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìfẹ́ àti òdodo pa ọba mọ́,nípa ìfẹ́, ìtẹ́ rẹ̀ wà láìléwu.

Òwe 20

Òwe 20:18-30