Òwe 19:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwà òmùgọ̀ ènìyàn fúnra rẹ̀ a pa ẹ̀mí rẹ̀ run;ṣíbẹ̀ ọkàn rẹ̀ yóò máa bínú sí Olúwa.

Òwe 19

Òwe 19:1-7