Òwe 19:28-29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

28. Ajẹ́rìí tí ó bàjẹ́ máa ń kẹ́gàn ìdájọ́ òtítọ́ẹnu ènìyàn búburú sì ń gbé ibi mi.

29. A ti pèṣè ìjìyà sílẹ̀ fún ẹlẹ́gàn;àti pàṣán fún ẹ̀yìn aláìgbọ́n.

Òwe 19