Òwe 19:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ohun tí ènìyàn ń fẹ́ ni ìfẹ́ tí kì í yẹ̀;ó sàn láti jẹ́ talákà ju òpùrọ́ lọ.

Òwe 19

Òwe 19:18-28