Òwe 19:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A máa ń jogún ilé àti ọrọ̀ lọ́dọ̀ òbíṣùgbọ́n aya olóye láti ọdọ̀ Olúwa ni.

Òwe 19

Òwe 19:10-23