Òwe 19:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sàn kí èèyàn jẹ́ tálákà tí ìrìn rẹ̀ kò lábùkù ju aláìgbọ́n tí ètè rẹ̀ jẹ́ àyídáyidà.

Òwe 19

Òwe 19:1-2