Òwe 17:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti bí aláìgbọ́n lọmọ a máa fa ìbànújẹ́ ọkànkò sí ayọ̀ fún baba ọmọ tí kò gbọ́n.

Òwe 17

Òwe 17:11-24